@Adetoroakeem
E so fun alaso igbalode ko se jeje....
E so fun alagbara aye ko rora se .......
E so fun kii-gbo kii-gba pe ile n yo.......
E so fun Baba/iya olowo pe yoo d'opin
Aimo'ye idi ileke ni saare
Aimo'ye Arewa ati Gbajumo ti ko si mo
Eni ti a jijo se ana n ko? Won ti di eni itan
Aimo'ye ayanfe/ololufe ti won ti fi Late siwaju oruko won....
Ki wa ni a wa n wa ile aye m'aya si gan na?
E ranti pe ohun gbogbo ni yoo pada di itan.
Olorun nikan ni yoo ku......
E je ka gbe ile aye se rere.........