23 w - Translate

Prayer to Ori
Orí nikan
Ló tó Alásaán bá ròkun
Bí mo bá lówó lówó
Orí ni n ó rò fún
Ori mi, iwo ni
Bi mo bá bímo láyé
Orí ni n ó rò fún
Ori mi, iwo ni
Ire gbogbo
tí mo bá ri láyé
Orí ni nó rò fún
Ori i mi, iwo ni
Orí pelé
Kò sóò sà tíi dánií gbè
Léyin orí eni
Orí mii àbí yè
Eni orí bá gbebo rè
Kó yò sèsè
Ase.